AGBAGBA NJUBA By Dynamic Dammie
CHORUS
Oh, eh ………
(We bow down to you)
(Lord we bow down to you)
Agbagba wọn júbà
Awon ọrùn wọn júbà
Fun ẹni to laiye
Fun eni to lọ’run
Agbagba won juba rẹ
Awon ọrùn wọn juba re
Fun ẹni to laiye
Fun eni to lọ’run
Solo
Angels are falling down at your throne,
The Kings are bowing down before you,
Ìwọ nikan lo ni ẹmi eniyan
Ìwọ nikan lo ni
Angels are falling down at your throne,
Kings are bowing down before you,
Ìwọ nikan lo logo
Ìwọ nikan lo ni eyẹ̀
CHORUS
Agbagba won juba
Awon ọrùn wọn juba
Fun ẹni to laiye
Fun eni to ni ọrùn
BRIDGE
Àwọn aye nke
Mímọ mimọ o mímọ
Fun ẹni to ni ìbẹrẹ fun ẹni to lopin 3x
LEAD VOCAL
Agbagba won juba
Awon ọrùn wọn juba
Fun ẹni to laiye
Fun eni to lọ’run