DOWNLOAD MP3: God’s Mercyy – Mo Farapamo (Lyrics). Newcomer gospel music artist and songwriter, God’s Mercyy releases her debut single she title “Mo Farapamo.” A Yoruba song which translate as “I’m Hidden”.
Listen, download and enjoy.
Lyrics: written by God’s Mercyy
Mo farapamo
Jesu Mofarapamo
Mofarapamo sinu re
Mo faramipamo
Olori aye Mofarapamo
Mofarapamo sinu re
Nitori
Orisirisi nkon lo sele laye
Mofaramipamo
Orisirisi nkon lo sele laye
Jesu Mofarapamo sinu re
Mo njade layo
mo nde layo
anu morigba lowo baba mi
gbogbo imota oti di asan
Mofarapamo sinu re
aye opolopo ti sofo
emi oyowon
aanu re lo gbe mi ro
Orisirisi nkon lo sele laye
Jesu Mofarapamo sinu re
opolopo sun sile iwosan
opolopo ja si iku lowo
Orisirisi nkon lo sele laye
Jesu Mofarapamo sinure
Mofarapamo
Jesu Mofarapamo
Mofarapamo sinu re
Mofarapamo Olori aye Mofarapamo
Mofarapamo sinure