IBINU SINMI LAYA WERE By Tope Alabi
This wonderful song is an exposition to the detrimental effects of anger. Anger Lies in the Boson of the fool such as the song implies. Anger has a way of destroying things built with efforts and even destroy the builders. Here is a didactic song you will love.
Click the below button to download the song now (6mb)
LYRICS:
Ibinu simi laya were
O se kondo
O se kumo kan
Ebo ti kale s’orita f’Esu
Ase nla be sile nile iku
Ilekun si o o, fun ‘jamba
E wose Satani eeni eko
(Ibinu simi)
Ebo ti kale s’orita f’Esu
Ibinu simi laya were (laya were)
O se kondo (o o o)
O se kumo kan
Ebo ti kale s’orita f’Esu (Eh ee)
Ase nla be sile nile Iku (nile Iku)
Ilekun si o o, fun jamba (Ewo se o)
E wose Satani eeni eko
Ibinu a maa simi laya were
Enikeni to nbinu wa d’ore Esu
On kanna ni yo jomoodo Esu
Bo ti nlu ni kondo ni yo ma gba kumo
A mi a gbebo f’Esu lorita ni gbogbo igba
Yo ma pe apeje fun lojoojo
Onibinu losi lekun fun ‘jamba
To fi nwole saye won beeni.
(Beeni)
Ibinu simi laya were (boo tiri niyen o)
O se kondo (ooo)
O se kumo kan (ibinu)
Ebo ti kale s’orita f’Esu (ko dara laya eniyan)
Ase nla be sile nile iku (ooo)
Ilekun si o o, fun jamba (A maa faniya pere pere)
E wose Satani eeni eko
Ibinu simi laye were
Beeni Bibeli mi wi fun mi
Oko to nbimu lu ‘yawo e se lese e
Iyawo to nbinu ba nkan ini je
Oninu fufu to nja ni hoho ladugbo
Won ki i pe so onibinu loruko
Bi won o pe ni were, won a pee ni Esu
Beeni ire nsa fun oninu fufu
Eto Satani f’ aye awon eda kan ni
E tete se ipinu ko to di abode
(Ko to di abode)
Ibinu simi laya were (eee)
O se kondo (ooo)
O se kumo kan (eto Olorun ko ni yen fun o)
Ebo ti kale s’orita f’Esu (tete se ipinu)
Ase nla be sile nile iku (O fe fi gba ohun rere lowo e)
Ilekun si o o, fun jamba (aaa)
E wose Satani eeni eko (ise Satani ni)
Asiko re e o eyan, e lo yi pada
Onibinu tin lu omo lai dake
Oninu fufu elepe to nsepe f’omo
T’omo ba dagba tan, a ma gbogun epe kiri
Angeli tohun gbere bo, to ba e ba ibinu
Ko ni le duro, a yaa fese fe
O le ma s’ogun aye, ko je iwo fun rare
Enito fogun jara e tio mo yo a se gbo
E gbadura e, ke jawo
Ko lere gidi, ibinu a ma a pani
(Ohun pani)
Ibinu simi laya were (a maa muni paniyan)
O se kondo
O se kumo kan (alu daku)
Ebo ti kale s’orita f’Esu (edi aye, edi ara eni)
Ase nla be sile nile iku (loruko Ibinu je)
Ilekun si o o, fun jamba (ee ya sora o)
E wose Satani eeni eko (kire ma foyin ru)
Ibinu a ma ba ohun rere je o
(Oooo lojokan o dandan)
Inu buburu a maa muni saisan o
(Eee lojokan e gbo)
Inu fufu ki i je kire o kan ni
(Oooo lojokan o dandan)
Obinu filaka fagbada d’ana nu
(Eee lojokan o dandan)
Akona ran aso botiwu koo gbon o
(Oooo lojokan o dandan)
E lo so’wa yin wu, ibinu ki sohun ire
Ibinu eniyan kii se se ododo Olorun
(Oooo lotito o e gbo)
Eni to lora lati binu sanju alagbara lo
(Eee lotito o e gbo)
Enito sakiso emi san ju eni to segun odidi ilu
(Oooo lotito o e gbo)
Otan lawon alagbara ma mero
(Eeee lotito o e gbo)
Ibinu safihan ailera bi i were
(Oooo lotito o e gbo)
Ipamora nsafihan okun Olorun