DOWNLOAD MP3: Olusolade Oyetunde – ìre Odún TunTun. Gospel Music Minister Yetunde Olusolade is out with her first single titled ‘IRE ODUN TUNTUN’ means “Blessing for the New Year”
According to her; Being positive and confessing good things should be an habit of every believer . “Ìre Odún Tuntun” is a song of blessings – confessing good and positive things into our lives in the existing and the coming year. A song that will bring testimonies into our home, work, business, spiritual lives, etc.
Olusolade Oyetunde – Ìre Odún Tuntun Lyrics
Chorus:
Odún to n bo, a ba mi laye o
Ire gbogbo a je titemi
Loruko Jesu mi o ni sokun o
Ninu Odún tuntun, ayo laraye a ba mi yo.
Olorun to da aye, a fadun soro mi
Gbogbo ikoro patapata, a bami mu kuro
Lori oko, lori omo, ayo mi a po so
Ninu odun tuntun, ayo l’araye a ba mi yo.
Iro ayo la o ma gbo ninu ago mi
Gbogbo ona to ti wo, l’Olorun a ba mi to
Anito, aniseku, ninu ile mi
Ninu odun tuntun, mi o ni salaini o.
Ati se ife Olugbala, ko ni nimilara
Igbe aye emi mi, a maa dagba so
Ninu odun tuntun, aye mi a yin Olorun l’ogo.