ORUKO JESU By Bukola Ore Ofe Jesu
Description:
There is a name that is above all other names that can be mentioned on earth, under the earth and every where. The name of Jesus! “Oruko Jesu” is a spirit filled track that is birth in the place of fellowship with God. It is a lyrical representation of the mightiness and greatness of the name of Jesus. I believe that as you will call on the name of Jesus, Your life shall experience the required turnaround. Listen to the track and you will blessed.
Biography:
Lady Evangelist Bukola Emmanuel (born 16. February) Simply known by her stage name “Bukola Ore Ofe Jesu”, is a Nigeria gospel minister, Songwriter, recording artist. She studies Economics mathematics at the Taisolarin College of education Ogun State. Bukola started singing at Anglical church as a Choir and later became the Choir leader at Taisolarin College of education (CMPD). She started her professional music career at the way of life evangelical ministries where she started her “His Gracespeaks music ministries“..
DOWNLOAD ORUKO JESU By Bukola Ore Ofe Jesu
Size: 14mb
581 Downloads
Song lyrics :
Intro:
Agbara nbe lafefe
Agbara nbe ninu Omi
Agbara nbe nibi gbogbo, Oruko Jesu tawonyo
Oriki ;
Baba mi ti Ose gbamu, beni kose juule
Baba mi ninatin opapa, Papaogbodo rum Ina osi gbodoku.
Anse kabiosifobaalade aye egbo Kilawafeso fobatofiwonje o
Igi kan ṣoṣo temimo tele gberin duro lori Omi,
Agbara Ori agbeleba to soraredole tinwo koban koban koban, egbo iru awodu wo lafefun
Okutigba’wodu ohun na, eni kinimbe lara awodu oun? Odo aguntan Olorun toko ese araye of the year bisiṣengba niyen tiyiosimagba forever
Baami ooo, tin baki o lorikiyi ti o jade simi, a je pe o setan ati fun mi loriki titun nu, Ibi agbara eniyan Parisi, ibe ni agbara ti e bere oo,
Babami buserin, ogun aye busekun, babami busekun nitori Komo araye le rerin
Epe ni erinmi nla tin tele togo tewa tola tiyanu tiyanu, Orin ile aye mi titi, Ba tun wa pe n Kiniun eyajuda, ese mistake, mistake Ibe ni ki eyin emi esu o duro ki ofa yinya pere pere.
Oun laditu, oun nijinle, oun lojiji eja odo lenu baba lola, oun lojo tin ro wayiwayi losodi ti o de iyapaja • Ara to ba wu o olodumare lon da oo.
Aye okuku da o mo lo nfi npe o ni omo dafidi, humm, won okuku paro sugbon 0 ju oun ti eniyan kanlebilo, eti a so re bo aye mo le lan fin pe ni sanmo
Ori aye oun lokuku gbe ese re le lori, eru re freshi lojojumo lanfin pe o le rujejeeeee….
Chorus 1 ; Oruko Jesu lokomiyo(2x) Gbati Satani gbeserede Oruko Jesu lokomiyo
Verse 1; Loruko Jesu Kigbogbo ekun ma wole
berin ba kan erin, Ikan a tee fun kan ni
Lorun laye denu ile kosoruko miran, ORUKO JESU olagbara
Loruko re mobo lowo ogun a fogo sofo
Loruko re mobo lowo ogun ejemi (lowo ogun ejemi)
Egun pare epe pare Lori oro mi
ORUKO JESU lokomiyo
Verse 2 : Oruko re lo gbe gbogbo oruko mi,
Agbara re lonje awon agbara, agan poruko re o pada pomo ran nise, ORUKO JESU yi ongbani la.
loruko yi ladari eseji, oruko Jesu niku to npaku nigbatiku ojiji gbe ise re de ORUKO JESU yi lokomiyo
Chorus 2 ; Jesu alanu mi ose oo baba Aileyipada ose oloruko ayo
Verse 1; Oloruntoforin ayosimi lenu iwoloyelatima fogo fun , unchangeable changer ose oloruko ayo
Call ; Emi Ore Ofe Jesu module — Resp; Ose oo baba
Call ; Lowo Alade wura — Resp ; Ose oloruko Ayo
Call ; Olorun Ododo eye ose — Resp ; Ose oo baba
Call ; Aileyipada — Resp ; Ose oloruko ayo
Chorus 3 ;You are yaweh, we call you yaweh
Toriwoloso pe kin mayo. Ayonilenu yawere (mopase kiwo aninilara koyawere)
Chorus 4 ; Eba mi di pa o Jesu gbogbo ona taye le gbamumi
Verse 1 ; Ojuti tota to le mi loju aye to mo fo won le fe gboju ala mumi bami tewon pa
Verse 2 ; Tori ogo tori future timoni lonfo won lori, ekon fojujo kiniun no eoleyin.
Verse 3 ; Enitowakoto fun ni emi re laofidi, eni ba fi ida pani laofida pa
Verse 4 ; Bi modekai bajomo juu o le bori, Soun niyawo amani Sofun oko re ko to te
Verse 5 ; Pharao to gbiyanju re oti donje eja, Herodu to gbiyanju re oti di ounje idin
Verse 6 ; Ebamidipa ooo Emimimo gbogbo koto to to ti gbe folore mi