DOWNLOAD MP3: SOLA ALLYSON – ORO OLUWA (SONG+ LYRICS)
Oro Oluwa (The words of God) is a song that tells about the efficiency and the potency of the word of God. It addresses the issue of the word of the Lord tarrying yet it will not go back to God unfulfilled. God will never speak a word that will not come to pass. Whatever God has said concerning you in the past will surely come to pass, the only thing you need to do is to listen this song as it will help strengthen your FAITH IN GOD…………….SHALOM.
Audio Player
Oro Oluwa
Ọrọ’ Olúwa kòni lọ láì ṣẹ’
Ìfẹ’ Olúwa kòní lọ láì ṣẹ’
Ìmọ’ Olúwa kòni lọ láì ṣẹ’
Òun mo rí yẹ kó ba mí lẹ’ru
Òun mo rí yẹ kó mì mí lọ’kàn
Oti lẹ’ yẹ kó fò mí láyà
Ṣùgbọ’n mo pinnu láti dí imú Ọlọrun òdòdó ni
Sii bẹ mo pinnu láti mọ kan ro t’ori mo mọ pé Ọ’rọ’ Olúwa, kò ní lọ láì ṣẹ’
Ìfẹ’ Olúwa kó ni lọ láì ṣẹ’

Kò ní lọ láì ṣẹ’
Kò ní lọ láì ṣẹ’
Ìgbàgbọ’ rẹ lo ń béèrè
Ìlérí a má ṣẹ’
Hmmmmm…
Kò ní lọ láì ṣẹ’
Ìgbàgbọ’ rẹ lo ń béèrè
Ìlérí a má ṣẹ’
Hmmmmm…
Ìbànújẹ’ lè wá síbẹ’ ọ’rọ’ rẹ á ṣẹ’
Ìkorò lè pọ’ o ṣùgb ‘adun la ja si
Mo gbójú mí ṣá pá òkè
Iranwọ’ mí n bẹ láti ọ’dọ’ Ọlọ’run òdòdó
Ìdánilójú yí mú ‘retí wá t’ori mó mọ pé
Ọ’rọ’ rẹ sì mí (hmmm) kò ní lọ láì ṣẹ’
Ìfẹ’ rẹ’ sí mí réré ni kò ní lọ láì ṣẹ’
Ìmọ’ Olúwa kó ni lọ láì ṣẹ’

Ọlọ’run kìí ṣ’ ènìyàn tó máa ṣe ké
Oti wí bẹ’ àṣẹ bẹ dandan lo jẹ’
Bó tilẹ’ wù kó rí ọ’rọ’ rẹ àṣẹ
Olè pẹ’ díẹ’ ṣùgbọ́n pé kò yẹ (hmmm) rárá rárá
Òfìfo á dọ” pọ ìrora á di’ rọrùn ká ní ‘retí
Adùn aapọ’ aapẹ’
A fi rí gidi a fẹ’rẹ’ẹ’ gẹ’dẹ’ àpẹẹ

Ìgbàgbọ’ rẹ kò má mi sẹ ìlérí àṣẹ
Ìgbàgbọ’ rẹ kò má mi sẹ ìlérí a má ṣẹ
Ìgbàgbọ’ rẹ kò má mi ṣẹ ìlérí àṣẹ
Ìgbàgbọ’ rẹ kò má mi sẹ ìlérí a má ṣẹ
Ìgbàgbọ’ rẹ kò má mi ṣẹ ìlérí àṣẹ
Òun órí lè má ba ọ’ lẹ’ru
Òun órí lè má mi ọ lọ’kàn
Oti lẹ’ yẹ kó fò ọ láyà
Ṣùgbọ’n ko pinnu láti dí imú Ọlọrun òdòdó ni
Sii bẹ pinnu láti mọ kan ro t’ori àjọ mọ ní pé
Ọ’rọ’ rẹ sì wá réré ní (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Ìfẹ’ Olúwa sì wá réré ni (Kó ni lọ láì ṣẹ’)
O kan jọ búburú ni koni burú fún ọ ọmọ ènìyàn ọ’rọ’ rẹ kii yẹ (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Mójú kúrò nínú Júù Júù tó yọ ká gbójú rẹ sókè iranwo àwa (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Òun ni lọ’wọ’ lọ’wọ’ iranlọwọ nígbà tó wà àti ‘gbá tí ó wà ọ’rọ’ rẹ kò ní lọ láì ṣẹ’ (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Gba lolu gbá lolu tọ gbá l’ olùkọ’ at’ olùdarí ọ’rọ’ rẹ réré ni (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Eh! Ọ’rọ’ Olúwa (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Níwọ’n ìgbà tí mo gbẹ’ kẹ’l ‘olú èmi ó ní rí’ tijú kan lai lai lai (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Mo gbà lólu ‘rán lọ’wọ’ mi ò mọ l’ àrán mi lọ’wọ’ ọ’rọ’ rẹ kò ní láì ṣẹ’ (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Oti wí bẹ’ẹ’ àṣẹ bẹ’ẹ’ fún mi mo dúró mo dúró (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Eh! Eh! Eh! Ọ’rọ’ Olúwa o (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Koni lọ láì ṣẹ’ kò ní lọ láì ṣẹ’ gbà bẹ gba bẹ (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Eh! Eh! Eh! Ọ’rọ’ rẹ siwa ó rere ní (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Tújú rẹ ká tújú rẹ ká ọ’rọ’ rẹ kò ní lọ láì ṣẹ’ (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Lábẹ’ bó tilẹ’ wù kori ọ’rọ’ rẹ kọ’ni lọ láìṣe gbà bẹ (Kò ní lọ láì ṣẹ’)
Hmm… Ọ’rọ’ Olúwa ó (Kò ní lọ láì ṣẹ’)