OLORUNTOBA AYOMIKU MICHAEL, hails from Kogi State, Nigeria. He is a praise and worship leader and a lover of the Most High God. OTISE means he has done it in Yoruba. A song from the gratitude album for the grateful. His first album “Gratitude” was launched in April 2021. Click here to download O TISE by Ayo Mike (9mb)
LYRICS
Chorus
Oti se baba ti soro mi dayo/2×
Egan ojosi baba ti se gan yi dogo
Ekun ojosi Oluwa nu omije minu Araiye ebami yo moti ni Jesu lolugala
Eniyan ebami Jo motini Jesu lolugbeja Hallelujah
Verse 1
Ara ebamijo Olorun ti soro mi dayo
Emi eni aiye ti ro pin Oluwa gbe ori mi soke
Igba won sebotan Onise ara lowo iyanu
Ara ebami jo o
Moti ni Jesu lolugbala Hallelujah
Chorus
Oti se baba ti soro mi dayo/2×
Egan ojosi baba ti se gan yi dogo
Ekun ojosi Oluwa nu omije minu Araiye ebami yo moti ni Jesu lolugala
Eniyan ebami Jo motini Jesu lolugbeja Hallelujah
Verse 2
Ore ma ronu mo Olugbala ayoju soro re Ma sore ti nu Jesu yio ko gbagbe re
Oba to se ti hanna ati Jebesi nbe laiye Sati gbokanrele alanu loluwa
(Aba o se o asore re dayo)/2* shoti gbo
(Chorus then percussion)
Oti se baba ti soro mi dayo/2×
Egan ojosi baba ti se gan yi dogo
Ekun ojosi Oluwa nu omije minu Araiye ebami yo moti ni Jesu lolugala
Eniyan ebami Jo motini Jesu lolugbeja Hallelujah
Soloist (vamp)
Oti se o baba ti se o/2*Ohun to nba mi lenu baba ti se o
What no man can do he has done it for me, What no man has done
Jesus did it for me/5*
Vamp
Oti se baba ti soro mi dayo/2×
Egan ojosi baba ti se gan yi dogo
Ekun ojosi Oluwa nu omije minu Araiye ebami yo moti ni Jesu lolugala
Eniyan ebami Jo motini Jesu lolugbeja Hallelujah